LG 29FU6RLM User Manual Page 47

  • Download
  • Add to my manuals
  • Print
  • Page
    / 60
  • Table of contents
  • TROUBLESHOOTING
  • BOOKMARKS
  • Rated. / 5. Based on customer reviews
Page view 46
11
TOP text (iyan)
Itọsọna yio fi fi aye merin han; pupa, alawo ewe,
yẹlo ati bulu ni abe oju iran. Yẹlo tunmọsi ipele
kan, bulu yu tunmọsi bulọku tokan.
Bọrọgidi/
ęlęgbę/
abala yiyan
1. Pẹlu bọtini bulu o le tesiwaju lori block kan si
keji.
2. Lo bọtini yẹlo lati tesiwaju lori group to kan.
3. O le tesiwaju lori oju ewe ti o wa lori ẹ nipa titẹ
bọtini alawọ ewe yo fun ararẹ bọ si group to
kan.
Bakan naa bọtini
D
wulo.
4. Bọtini pupa fun o laye lati pada si idawọle
ateyin wa. Bakan ńaa bọtini
E
seé lo.
Inawogan oju ewe ni gere
Pélu ibasepọ si SIMPLE teletext, o le nawọ gan
oju ewe nipa fifi nọmiba mẹta si nu bọtini NỌMIBA
ninu isẹ TOP.
FASTEXT
Awọn oju ewe teletext jẹ alawọ lẹbaa isalẹ oju iran,
a si le dawọ lẹ eyi nipa tite bọtini alawọ.
Inawọ gan oju ewe
1. Te bọtini
E lati nawọ gan oju ewe index.
2. O le nawọ gan oju ewee alawọ lebaa isale pẹlu
bọtini alawọ kan ńaa.
3. Pẹlu ibasepọ si SIMPLE teletext, o le nawọ
gan oju ewe nipa fifi nọmiba mẹta si nu bọtini
NỌMIBA ninu isẹ FASTEXT.
4. Bọtini
D
/
E
seé lo lati nawọ gan oju ewe.
Asayan sisẹ teletext
REVEAL
Tẹ bọtini yii lati ni anfani si awọn itọnisọna to wa
lapamọ, bu atunse si ijakule tabi wahala.
Tẹ bọtini yii lẹẹkan si lati gbe itọnisọna yii kuro loju
iran.
SIZE
Yan text oni sipo meji giga.
Tẹ bọtini yii lati jẹ ku oju ewe yii tabi.
Tẹ bọtini yii lẹẹkan si lati jẹ ki idaji oju ewe yii tobi.
Tẹ bọtini yii lẹẹkun si lati daa pada si oju iran ati
bẹrẹ wa.
UPDATE
Eyi ma n je ki aworan TV yii jẹyọ loju iran. yio
jẹyọ la pa osi oke oju iran ẹrọ yii. Nigbati oju ewe
ti o gbe yẹwo ba wa fun lilo, to ba jẹyọ yio
yi pada si nọmiba oju ewe. Tẹ bọtinu lati ri agbe
yẹwọ.
HOLD
Eyi ma n da iyipada oju ewe duro tio ma n sẹlẹ
ni gbati oju ewee teletext ba ni oju ewe meji tabi
jubẹẹ lọ.
Nọmiba awọn oju ewe ati oju ewe to jẹyọ ma n han
loju iran labẹ ago. Ti o ba te eyi, yio han lapa osi
oju iran, bi o ba tę bọtini yi amin duro yio won ni oke
opa osi awaron ati piparọ abala yio ni idiwọ.
Lati tesiwaju tẹ bọtini yii lẹẹkan si.
MIX
Eyi ma n fi oju ewe teletext han loju aworan TV.
Lati pa aworan TV tẹ bọtini yii lẹẹkan.
TIME
H
Ti o ba n wo eto lori ẹrọ TV yii, te bọtini yii lati fi
ago han lapaa otun oke oju iran ẹrọ yii. Tẹ bọtini
yii bakansi. Lati mu ifihan yii kuro. Ninu isẹ teletext,
nawọ gan nọmiba oju ewe. Nọmiba oju ewe yio han
ni isalẹ oju iran. Lati oju ewe pada te bọtini PUPA/
ALAWO EWE,
D
/
E
tabi bọtini NỌMIBA. Tẹ lekan
si lati gbe isẹ yii jade.
Teletext (iyan)
Page view 46
1 2 ... 42 43 44 45 46 47 48 49 50 51 52 ... 59 60

Comments to this Manuals

No comments