LG 29FU6RLM User Manual Page 41

  • Download
  • Add to my manuals
  • Print
  • Page
    / 60
  • Table of contents
  • TROUBLESHOOTING
  • BOOKMARKS
  • Rated. / 5. Based on customer reviews
Page view 40
5
Iba ni jomi toro oro laarin iwọ ati ẹrọ le waye pẹlu
awọn asayan yii. Bọtini to wa fun igbese lati sisẹ
lori ẹrọ yii jẹyọ pẹlu.
Yiyan asayan
1. Te bọtini
MENU ati bọtini
D
/
E
lati ri owun elo
kan kan loju iran.
2. Tẹ bọtini
G
ati bọtini
D
/
E
lati nawọ gan owun
elo kan.
3. Tẹ bọtini
G
lati fi owun elo to kun han.
4. Se atunto igbesoke silẹ owun elo pẹlu
F
/
G
tabi
D
/
E
.
O le lọ si owun elo to ga julo nipa titẹ bọtini
OK
tabi
F
ati lati lọ si ile nipa titẹ bọtini
G
.
Akiyesi :
a. Ninu isẹ teletext, owun elo o ki n juyọ.
b. Ninu awọn ẹya miran,
Normal
/
Turbo
search
o ni jẹyọ,
Start
nikan ni o jewo ninu
owun elo
Auto programme
.
c. Ninu awọn ẹya miran,
Tilt
,
Booster
tabi
Degauss
ko ni jẹyọ.
d. Ninu awọn ẹya miran,
Language
,
X-WAVE
ko ni jẹyọ.
TAN ati PA
1. Tẹ bọtini titan ati pipa lati muna wa si inu ẹrọ
yii.
2. Ti ẹrọ yii ba wa nipo idaduro tẹ bọtini
POWER,
D
/
E
,
TV/
AV tabi bọtini NỌMIBA lori rimotu
lati tanan lẹkun rẹrẹ.
3. Tẹ bọtini
POWER lori rimotu.
Ẹrọ yio pada si po idaduro.
4. Tẹ bọtini agbara lẹẹkun si lati pa ẹrọ yii pata
pata.
Akiyesi : Tio ba sẹlẹ ni pẹ ni wọngba ti o tan na
si ẹrọ yii okun ina rẹ o si nina ẹrọ yii yio wa nipo
iduro.
Mimu lo awọn eto
O le dawọle nọmiba eto kan pẹlu
D
/
E
tabi bọtini
NỌMIBA.
Didari ohun
Tẹ bọtini
F
/
G
lati gbe ohun soke tabi silẹ.
Q.VIEW (tabi YẸLO)
Tẹ bọtini
Q.VIEW (tabi YẸLO) lati wo eto ti o wo
gbeyin.
Isẹ idakẹje
Tẹ bọtini
MUTE. Eyi o sehun ẹrọ yii, yio si fi W
soju iran.
O lẹ di lọwọ nipa titẹ bọtini
MUTE,
F
/
G
,
I/
II/
*
(iyan).
Yiyan ede lori aworan
Owun elo le wa loju iran ni ede ti o fẹ kọkọ. Nawọ
gan ede tirẹ.
1. Tẹ bọtini
MENU ati bọtini
D
/
E
lati nawọ gan
owun elo to yatọ.
2. Tẹ bọtini
G
lati nawọ gan Language.
3. Tẹ bọtini
G
ati
D
/
E
lati nawọ gan ede to wu o.
Gbogbo owun ti o han lori oju iran yio wa ni ede
ti o ti nawọ gan. Tẹ bọtini
OK ati bọtini
F
lati
nawọ gan owun elo to yatọ.
4. Tẹ bọtini
MENU lera lera lati pada si ipo akọkọ
TV yii.
AGBARA RE (TAN/
PA)
eyi wa fun titan ati pipa ẹrọ yii.
AFIHAN AGBARA/
IDADURO
eyi ma n tan yo nigba ti ẹrọ ba wa nipo aise
owu kowu.
ina yi yio wa se baibai nigbati a ba tan tan.
OHUN TI O DARI RẸ TI A NPE NI SENSO
Akiyesi : Rimotu ti o ba ẹrọ yii wa ni kan ni yio
ba ẹrọ yii sisẹ. (Ti o ba lo omiran wọn ko ni
sisẹ daradara.)
MENU
inawọ gan owun elo.
OK
eyi jẹ itẹwọ gba si owun tun tun ti o se lori ẹrọ yii.
F
/
(Ohun Sodo/
Soke)
idari ohun.
idari owun elo.
D
/
(Eto Soke/
Sodo)
inawọ gan eto tabi owun elo kan.
fifi ina si ẹrọ ni po iduro.
Sọkẹti AUDIO/VIDEO/USB IN (AV IN2)
(iyan)
fi audio/video/USB sọkẹti ita ti awọn ẹya ita si
sọkẹti yii.
Akiyesi :
Aworan yii jẹ afiwe iwaju tabi ẹgbẹ paneli.
Aworan yii lee yatọ si ẹrọ rẹ.
Aye ati isẹ isakoso
Koko isẹ sisẹ
Owun elo oju iran
Page view 40
1 2 ... 36 37 38 39 40 41 42 43 44 45 46 ... 59 60

Comments to this Manuals

No comments